Hósíà 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Iye àwọn èèyàn* Ísírẹ́lì máa dà bí iyanrìn òkun tí a kò lè díwọ̀n tàbí tí a kò lè kà.+ Níbi tí a ti sọ fún wọn pé, ‘Ẹ kì í ṣe èèyàn mi,’+ a ó pè wọ́n ní, ‘Àwọn ọmọ Ọlọ́run alààyè.’+
10 “Iye àwọn èèyàn* Ísírẹ́lì máa dà bí iyanrìn òkun tí a kò lè díwọ̀n tàbí tí a kò lè kà.+ Níbi tí a ti sọ fún wọn pé, ‘Ẹ kì í ṣe èèyàn mi,’+ a ó pè wọ́n ní, ‘Àwọn ọmọ Ọlọ́run alààyè.’+