Jẹ́nẹ́sísì 13:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀, tó fi jẹ́ pé tí ẹnikẹ́ni bá lè ka erùpẹ̀ ilẹ̀ ni wọ́n á tó lè ka+ ọmọ* rẹ. Jẹ́nẹ́sísì 22:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 ó dájú pé màá bù kún ọ, ó sì dájú pé màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti iyanrìn etí òkun,+ ọmọ* rẹ yóò sì gba ẹnubodè* àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lọ́wọ́ wọn.
16 Màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀, tó fi jẹ́ pé tí ẹnikẹ́ni bá lè ka erùpẹ̀ ilẹ̀ ni wọ́n á tó lè ka+ ọmọ* rẹ.
17 ó dájú pé màá bù kún ọ, ó sì dájú pé màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti iyanrìn etí òkun,+ ọmọ* rẹ yóò sì gba ẹnubodè* àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lọ́wọ́ wọn.