-
Jeremáyà 32:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Àmọ́, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, o ti sọ fún mi pé, ‘Fi owó ra ilẹ̀ náà fún ara rẹ, kí o sì pe àwọn ẹlẹ́rìí wá,’ bó tilẹ̀ jẹ́ pé, a ó fi ìlú náà lé ọwọ́ àwọn ará Kálídíà dájúdájú.”
-