Àìsáyà 48:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ ti gbọ́, ẹ sì ti rí gbogbo èyí. Ṣé ẹ ò ní kéde rẹ̀ ni?+ Láti ìsinsìnyí lọ, màá kéde àwọn ohun tuntun fún ọ,+Àwọn àṣírí tí mo pa mọ́, tí o kò mọ̀.
6 Ẹ ti gbọ́, ẹ sì ti rí gbogbo èyí. Ṣé ẹ ò ní kéde rẹ̀ ni?+ Láti ìsinsìnyí lọ, màá kéde àwọn ohun tuntun fún ọ,+Àwọn àṣírí tí mo pa mọ́, tí o kò mọ̀.