2 Kíróníkà 36:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹni ọdún mọ́kànlélógún (21) ni Sedekáyà+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlá (11) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ Jeremáyà 37:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Ọba Sedekáyà+ ọmọ Jòsáyà bẹ̀rẹ̀ sí í jọba ní ipò Konáyà*+ ọmọ Jèhóákímù, nítorí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì fi jẹ ọba ní ilẹ̀ Júdà.+
11 Ẹni ọdún mọ́kànlélógún (21) ni Sedekáyà+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlá (11) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+
37 Ọba Sedekáyà+ ọmọ Jòsáyà bẹ̀rẹ̀ sí í jọba ní ipò Konáyà*+ ọmọ Jèhóákímù, nítorí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì fi jẹ ọba ní ilẹ̀ Júdà.+