ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 1:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ẹ wẹ ara yín, ẹ jẹ́ kí ara yín mọ́;+

      Ẹ mú ìwà ibi yín kúrò níwájú mi;

      Ẹ jáwọ́ nínú ìwà burúkú.+

  • Jeremáyà 25:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Wọ́n ń sọ pé, ‘Ẹ jọ̀wọ́, ẹ yí pa dà, kí kálukú yín kúrò nínú ọ̀nà búburú rẹ̀ àti kúrò nínú ìwà ibi rẹ̀,+ kí ẹ lè máa gbé títí láé lórí ilẹ̀ tí Jèhófà ti fún ẹ̀yin àti àwọn baba ńlá yín tipẹ́tipẹ́.

  • Ìsíkíẹ́lì 18:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 “‘Torí náà, màá fi ìwà yín dá kálukú yín lẹ́jọ́,+ ilé Ísírẹ́lì,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí. ‘Ẹ yí pa dà, àní ẹ yí pa dà pátápátá kúrò nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ yín, kí wọ́n má bàa di ohun ìkọ̀sẹ̀ tó máa mú kí ẹ jẹ̀bi.

  • Hósíà 14:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “Pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, ìwọ Ísírẹ́lì,+

      Torí àṣìṣe rẹ ti mú kí o kọsẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́