- 
	                        
            
            Jeremáyà 7:5-7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Tí ẹ bá tún ọ̀nà yín àti ìwà yín ṣe lóòótọ́, tó bá sì jẹ́ pé òótọ́ lẹ ṣe ìdájọ́ òdodo láàárín èèyàn kan àti ọmọnìkejì rẹ̀,+ 6 bí ẹ kò bá ni àjèjì lára àti ọmọ aláìlóbìí,* pẹ̀lú àwọn opó,+ tí ẹ kò ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀ ní ibí yìí, tí ẹ kò sì tẹ̀ lé àwọn ọlọ́run míì tó máa yọrí sí ìṣeléṣe yín; + 7 nígbà náà, màá jẹ́ kí ẹ máa gbé ibí yìí, ní ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá yín títí láé.”’”* 
 
-