ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 32:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 mo sì fún Bárúkù,+ ọmọ Neráyà,+ ọmọ Maseáyà ní ìwé àdéhùn náà lójú Hánámélì ọmọ arákùnrin bàbá mi àti lójú àwọn ẹlẹ́rìí tó buwọ́ lu ìwé àdéhùn náà àti lójú gbogbo àwọn Júù tó jókòó sí Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́.+

  • Jeremáyà 45:2-5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nípa rẹ nìyí, ìwọ Bárúkù, 3 ‘O sọ pé: “Mo gbé! Nítorí pé Jèhófà ti fi ẹ̀dùn ọkàn kún ìrora mi. Àárẹ̀ mú mi nítorí ìrora mi, mi ò sì rí ibi ìsinmi kankan.”’

      4 “Kí o sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Wò ó! Ohun tí mo ti kọ́ ni màá ya lulẹ̀, ohun tí mo sì ti gbìn ni màá fà tu, ìyẹn gbogbo ilẹ̀ náà.+ 5 Ṣùgbọ́n ìwọ ń wá* àwọn ohun ńlá fún ara rẹ. Má ṣe wá wọn mọ́.”’

      “‘Nítorí mo máa tó mú àjálù wá bá gbogbo èèyàn,’*+ ni Jèhófà wí, ‘àmọ́ màá jẹ́ kí o jèrè ẹ̀mí rẹ* ní ibikíbi tí o bá lọ.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́