Jeremáyà 36:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 ó lọ sí ilé* ọba, sí yàrá akọ̀wé. Gbogbo àwọn ìjòyè* jókòó síbẹ̀: Élíṣámà+ akọ̀wé, Deláyà ọmọ Ṣemáyà, Élínátánì+ ọmọ Ákíbórì,+ Gemaráyà ọmọ Ṣáfánì, Sedekáyà ọmọ Hananáyà àti gbogbo àwọn ìjòyè yòókù.
12 ó lọ sí ilé* ọba, sí yàrá akọ̀wé. Gbogbo àwọn ìjòyè* jókòó síbẹ̀: Élíṣámà+ akọ̀wé, Deláyà ọmọ Ṣemáyà, Élínátánì+ ọmọ Ákíbórì,+ Gemaráyà ọmọ Ṣáfánì, Sedekáyà ọmọ Hananáyà àti gbogbo àwọn ìjòyè yòókù.