-
Jeremáyà 22:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nípa Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà nìyí,
‘Wọn kò ní ṣọ̀fọ̀ rẹ̀ pé:
“Áà, arákùnrin mi! Áà, arábìnrin mi!”
Wọn kò sì ní ṣọ̀fọ̀ rẹ̀ pé:
“Áà, ọ̀gá! Áà, kábíyèsí!”
-