Jeremáyà 36:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí sí Jèhóákímù ọba Júdà, ‘Kò ní lẹ́nì kankan tó máa jókòó sórí ìtẹ́ Dáfídì,+ òkú rẹ̀ á sì wà ní ìta nínú ooru lọ́sàn-án àti nínú òtútù lóru.+
30 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí sí Jèhóákímù ọba Júdà, ‘Kò ní lẹ́nì kankan tó máa jókòó sórí ìtẹ́ Dáfídì,+ òkú rẹ̀ á sì wà ní ìta nínú ooru lọ́sàn-án àti nínú òtútù lóru.+