Jeremáyà 21:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: “Wò ó, màá jẹ́ kí àwọn ohun ìjà tó wà ní ọwọ́ yín dojú kọ yín,* àwọn ohun tí ẹ fi ń bá ọba Bábílónì jà+ pẹ̀lú àwọn ará Kálídíà tí wọ́n dó tì yín lẹ́yìn odi. Màá sì kó wọn jọ sí àárín ìlú yìí.
4 ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: “Wò ó, màá jẹ́ kí àwọn ohun ìjà tó wà ní ọwọ́ yín dojú kọ yín,* àwọn ohun tí ẹ fi ń bá ọba Bábílónì jà+ pẹ̀lú àwọn ará Kálídíà tí wọ́n dó tì yín lẹ́yìn odi. Màá sì kó wọn jọ sí àárín ìlú yìí.