-
Jeremáyà 33:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Jèhófà bá Jeremáyà sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kejì, nígbà tó ṣì wà ní àhámọ́ ní Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́,+ pé:
-
-
Jeremáyà 38:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 wọ́n fi okùn náà fa Jeremáyà jáde, wọ́n sì gbé e gòkè kúrò nínú kòtò omi náà. Jeremáyà sì wà ní Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́.+
-