- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 3:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Àmọ́ Mósè sọ fún Ọlọ́run tòótọ́ pé: “Ta ni mo jẹ́, tí màá fi lọ bá Fáráò, tí màá sì mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní Íjíbítì?” 12 Ó fèsì pé: “Èmi yóò wà pẹ̀lú rẹ,+ ohun tí yóò sì jẹ́ àmì fún ọ pé èmi ni mo rán ọ nìyí: Lẹ́yìn tí o bá ti mú àwọn èèyàn náà kúrò ní Íjíbítì, ẹ máa jọ́sìn* Ọlọ́run tòótọ́ lórí òkè yìí.”+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        20 “Màá sọ ọ́ di odi bàbà tó lágbára sí àwọn èèyàn yìí.+ 
 
-