Jeremáyà 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Lónìí, mo ti sọ ọ́ di ìlú olódi,Òpó irin àti ògiri bàbà láti kojú gbogbo ilẹ̀ náà,+Láti kojú àwọn ọba Júdà àti àwọn ìjòyè rẹ̀,Láti kojú àwọn àlùfáà rẹ̀ àti àwọn èèyàn ilẹ̀ náà.+ Ìsíkíẹ́lì 3:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Mo ti mú kí iwájú orí rẹ dà bíi dáyámọ́ǹdì, ó le ju akọ òkúta lọ.+ Má bẹ̀rù wọn, má sì jẹ́ kí ojú wọn dẹ́rù bà ọ́,+ torí ọlọ̀tẹ̀ ilé ni wọ́n.”
18 Lónìí, mo ti sọ ọ́ di ìlú olódi,Òpó irin àti ògiri bàbà láti kojú gbogbo ilẹ̀ náà,+Láti kojú àwọn ọba Júdà àti àwọn ìjòyè rẹ̀,Láti kojú àwọn àlùfáà rẹ̀ àti àwọn èèyàn ilẹ̀ náà.+
9 Mo ti mú kí iwájú orí rẹ dà bíi dáyámọ́ǹdì, ó le ju akọ òkúta lọ.+ Má bẹ̀rù wọn, má sì jẹ́ kí ojú wọn dẹ́rù bà ọ́,+ torí ọlọ̀tẹ̀ ilé ni wọ́n.”