Àìsáyà 65:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kí Ọlọ́run òtítọ́* lè bù kúnẸnikẹ́ni tó bá ń wá ìbùkún fún ara rẹ̀ ní ayé,Kí ẹnikẹ́ni tó bá sì ń búra ní ayéLè fi Ọlọ́run òtítọ́* búra.+ Torí àwọn wàhálà* àtijọ́ máa di ohun ìgbàgbé;Wọ́n máa pa mọ́ kúrò ní ojú mi.+
16 Kí Ọlọ́run òtítọ́* lè bù kúnẸnikẹ́ni tó bá ń wá ìbùkún fún ara rẹ̀ ní ayé,Kí ẹnikẹ́ni tó bá sì ń búra ní ayéLè fi Ọlọ́run òtítọ́* búra.+ Torí àwọn wàhálà* àtijọ́ máa di ohun ìgbàgbé;Wọ́n máa pa mọ́ kúrò ní ojú mi.+