-
Jeremáyà 40:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nígbà tó yá, gbogbo olórí àwọn ọmọ ogun tó wà ní pápá pẹ̀lú àwọn ọkùnrin wọn gbọ́ pé ọba Bábílónì ti yan Gẹdaláyà ọmọ Áhíkámù ṣe olórí ilẹ̀ náà àti pé ó ti yàn án sórí àwọn ọkùnrin àti àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ kéékèèké tí wọ́n jẹ́ aláìní, tó ṣẹ́ kù sí ilẹ̀ náà, tí wọn ò kó lọ sí Bábílónì.+
-