Diutarónómì 32:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Torí Jèhófà máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn+ rẹ̀,Ó sì máa káàánú* àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Tó bá rí i pé okun wọn ti ń tán,Tó sì rí i pé àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́ àtàwọn tó ti rẹ̀ ló ṣẹ́ kù. Jeremáyà 18:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tí mo bá sọ pé màá fa orílẹ̀-èdè kan tàbí ìjọba kan tu, tí mo sọ pé màá ya á lulẹ̀, tí màá sì pa á run,+ 8 bí orílẹ̀-èdè náà bá jáwọ́ nínú ìwà burúkú rẹ̀ tí mo kìlọ̀ fún un, èmi náà á pèrò dà* lórí àjálù tí mo ti sọ pé màá jẹ́ kó dé bá a.+ Míkà 7:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+
36 Torí Jèhófà máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn+ rẹ̀,Ó sì máa káàánú* àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Tó bá rí i pé okun wọn ti ń tán,Tó sì rí i pé àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́ àtàwọn tó ti rẹ̀ ló ṣẹ́ kù.
7 Nígbà tí mo bá sọ pé màá fa orílẹ̀-èdè kan tàbí ìjọba kan tu, tí mo sọ pé màá ya á lulẹ̀, tí màá sì pa á run,+ 8 bí orílẹ̀-èdè náà bá jáwọ́ nínú ìwà burúkú rẹ̀ tí mo kìlọ̀ fún un, èmi náà á pèrò dà* lórí àjálù tí mo ti sọ pé màá jẹ́ kó dé bá a.+
18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+