2 Kíróníkà 24:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó ń rán àwọn wòlíì sáàárín wọn léraléra láti mú wọn pa dà wá sọ́dọ̀ Jèhófà, wọ́n sì ń kìlọ̀ fún wọn* léraléra, àmọ́ wọn ò gbọ́.+ Nehemáyà 9:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “Àmọ́, wọ́n ya aláìgbọràn, wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí ọ,+ wọ́n sì kẹ̀yìn sí Òfin rẹ.* Wọ́n pa àwọn wòlíì rẹ tó kìlọ̀ fún wọn láti mú wọn pa dà sọ́dọ̀ rẹ, wọ́n sì hu ìwà àìlọ́wọ̀ tó bùáyà.+ Sekaráyà 7:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ wọn ò fetí sílẹ̀,+ agídí wọn mú kí wọ́n kẹ̀yìn sí mi,+ wọ́n sì di etí wọn kí wọ́n má bàa gbọ́.+
19 Ó ń rán àwọn wòlíì sáàárín wọn léraléra láti mú wọn pa dà wá sọ́dọ̀ Jèhófà, wọ́n sì ń kìlọ̀ fún wọn* léraléra, àmọ́ wọn ò gbọ́.+
26 “Àmọ́, wọ́n ya aláìgbọràn, wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí ọ,+ wọ́n sì kẹ̀yìn sí Òfin rẹ.* Wọ́n pa àwọn wòlíì rẹ tó kìlọ̀ fún wọn láti mú wọn pa dà sọ́dọ̀ rẹ, wọ́n sì hu ìwà àìlọ́wọ̀ tó bùáyà.+
11 Àmọ́ wọn ò fetí sílẹ̀,+ agídí wọn mú kí wọ́n kẹ̀yìn sí mi,+ wọ́n sì di etí wọn kí wọ́n má bàa gbọ́.+