Jeremáyà 36:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jeremáyà bá pe Bárúkù+ ọmọ Neráyà, Jeremáyà sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí Jèhófà ti bá a sọ, Bárúkù sì ń kọ ọ́ sínú àkájọ ìwé náà.+ Jeremáyà 45:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ọ̀rọ̀ tí wòlíì Jeremáyà sọ fún Bárúkù+ ọmọ Neráyà nìyí, nígbà tó ń kọ ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà ń sọ fún un sínú ìwé+ ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà:
4 Jeremáyà bá pe Bárúkù+ ọmọ Neráyà, Jeremáyà sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí Jèhófà ti bá a sọ, Bárúkù sì ń kọ ọ́ sínú àkájọ ìwé náà.+
45 Ọ̀rọ̀ tí wòlíì Jeremáyà sọ fún Bárúkù+ ọmọ Neráyà nìyí, nígbà tó ń kọ ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà ń sọ fún un sínú ìwé+ ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà: