- 
	                        
            
            Jeremáyà 43:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Torí náà, Jóhánánì ọmọ Káréà àti gbogbo olórí àwọn ọmọ ogun pẹ̀lú gbogbo àwọn èèyàn náà kò ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà pé kí wọ́n dúró sí ilẹ̀ Júdà. 
 
-