-
Jeremáyà 2:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 ‘Ṣé ìránṣẹ́ ni Ísírẹ́lì àbí ẹrú tí wọ́n bí sínú agbo ilé?
Kí wá nìdí tí wọ́n fi kó ẹrù rẹ̀ lọ?
-
-
Ìsíkíẹ́lì 30:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Idà yóò dojú kọ Íjíbítì, ìbẹ̀rù á sì bo Etiópíà nígbà tí òkú bá sùn ní Íjíbítì;
Wọ́n ti kó ọrọ̀ rẹ̀, wọ́n sì ti wó ìpìlẹ̀ rẹ̀.+
-