Ìsíkíẹ́lì 29:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí náà, màá bá ìwọ àti odò Náílì rẹ jà, màá mú kí ilẹ̀ Íjíbítì dá páropáro kó sì gbẹ, yóò di ahoro,+ láti Mígídólì+ dé Síénè,+ títí dé ààlà Etiópíà. Ìsíkíẹ́lì 30:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Àwọn tó ń ti Íjíbítì lẹ́yìn pẹ̀lú yóò ṣubú,Agbára tó ń mú kó gbéra ga yóò sì wálẹ̀.’+ “‘Idà ni yóò pa wọ́n ní ilẹ̀ náà, láti Mígídólì+ dé Síénè,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.
10 Torí náà, màá bá ìwọ àti odò Náílì rẹ jà, màá mú kí ilẹ̀ Íjíbítì dá páropáro kó sì gbẹ, yóò di ahoro,+ láti Mígídólì+ dé Síénè,+ títí dé ààlà Etiópíà.
6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Àwọn tó ń ti Íjíbítì lẹ́yìn pẹ̀lú yóò ṣubú,Agbára tó ń mú kó gbéra ga yóò sì wálẹ̀.’+ “‘Idà ni yóò pa wọ́n ní ilẹ̀ náà, láti Mígídólì+ dé Síénè,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.