Ìsíkíẹ́lì 32:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 ‘Nígbà tí mo bá sọ ilẹ̀ Íjíbítì di ahoro, tí wọ́n kó gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀ lọ,+Nígbà tí mo bá pa gbogbo àwọn tó ń gbé inú rẹ̀,Wọ́n á wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.+
15 ‘Nígbà tí mo bá sọ ilẹ̀ Íjíbítì di ahoro, tí wọ́n kó gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀ lọ,+Nígbà tí mo bá pa gbogbo àwọn tó ń gbé inú rẹ̀,Wọ́n á wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.+