ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 41:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Torí pé èmi Jèhófà Ọlọ́run rẹ ń di ọwọ́ ọ̀tún rẹ mú,

      Ẹni tó ń sọ fún ọ pé, ‘Má bẹ̀rù. Màá ràn ọ́ lọ́wọ́.’+

  • Àìsáyà 43:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 43 Ohun tí Jèhófà wá sọ nìyí,

      Ẹlẹ́dàá rẹ, ìwọ Jékọ́bù, Ẹni tó dá ọ, ìwọ Ísírẹ́lì:+

      “Má bẹ̀rù, torí mo ti tún ọ rà.+

      Mo ti fi orúkọ rẹ pè ọ́.

      Tèmi ni ọ́.

       2 Tí o bá gba inú omi kọjá, màá wà pẹ̀lú rẹ,+

      Tí o bá sì gba inú odò kọjá, kò ní kún bò ọ́.+

      Tí o bá rin inú iná kọjá, kò ní jó ọ,

      Ọwọ́ iná ò sì ní rà ọ́.

  • Àìsáyà 44:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,

      Aṣẹ̀dá rẹ àti Ẹni tó dá ọ,+

      Ẹni tó ràn ọ́ lọ́wọ́ látinú oyún:*

      ‘Má bẹ̀rù, Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi+

      Àti ìwọ, Jéṣúrúnì,*+ ẹni tí mo yàn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́