Àìsáyà 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó ti gòkè lọ sí Ilé* àti sí Díbónì,+Lọ sí àwọn ibi gíga láti sunkún. Móábù ń sunkún torí Nébò+ àti torí Médébà.+ Wọ́n fá gbogbo orí korodo,+ wọ́n gé gbogbo irùngbọ̀n mọ́lẹ̀.+
2 Ó ti gòkè lọ sí Ilé* àti sí Díbónì,+Lọ sí àwọn ibi gíga láti sunkún. Móábù ń sunkún torí Nébò+ àti torí Médébà.+ Wọ́n fá gbogbo orí korodo,+ wọ́n gé gbogbo irùngbọ̀n mọ́lẹ̀.+