Nọ́ńbà 32:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì kọ́ Hẹ́ṣíbónì,+ Éléálè,+ Kíríátáímù,+ Àìsáyà 16:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí àwọn ilẹ̀ onípele Hẹ́ṣíbónì+ ti gbẹ,Àjàrà Síbúmà,+Àwọn alákòóso àwọn orílẹ̀-èdè ti tẹ àwọn ẹ̀ka rẹ̀ tó pupa fòò* mọ́lẹ̀;Wọ́n ti lọ títí dé Jásérì;+Wọ́n ti tàn dé aginjù. Àwọn ọ̀mùnú rẹ̀ ti tàn kálẹ̀, wọ́n sì ti lọ títí dé òkun.
8 Torí àwọn ilẹ̀ onípele Hẹ́ṣíbónì+ ti gbẹ,Àjàrà Síbúmà,+Àwọn alákòóso àwọn orílẹ̀-èdè ti tẹ àwọn ẹ̀ka rẹ̀ tó pupa fòò* mọ́lẹ̀;Wọ́n ti lọ títí dé Jásérì;+Wọ́n ti tàn dé aginjù. Àwọn ọ̀mùnú rẹ̀ ti tàn kálẹ̀, wọ́n sì ti lọ títí dé òkun.