Àìsáyà 63:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀.+ Ó wá di ọ̀tá wọn,+Ó sì bá wọn jà.+ Ìsíkíẹ́lì 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, màá rán ọ sí àwọn èèyàn Ísírẹ́lì,+ sí àwọn ọlọ̀tẹ̀ orílẹ̀-èdè tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+ Àwọn àti àwọn baba ńlá wọn ti ṣẹ̀ mí títí di òní yìí.+
10 Àmọ́ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀.+ Ó wá di ọ̀tá wọn,+Ó sì bá wọn jà.+
3 Ó sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, màá rán ọ sí àwọn èèyàn Ísírẹ́lì,+ sí àwọn ọlọ̀tẹ̀ orílẹ̀-èdè tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+ Àwọn àti àwọn baba ńlá wọn ti ṣẹ̀ mí títí di òní yìí.+