Jeremáyà 48:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 “‘Wọ́n á pa Móábù run, kò ní jẹ́ orílẹ̀-èdè mọ́,+Nítorí ó ti gbé ara rẹ̀ ga+ sí Jèhófà.