- 
	                        
            
            Jeremáyà 48:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        29 “A ti gbọ́ nípa ìgbéraga Móábù, ó gbéra ga gan-an, Nípa ìjọra-ẹni-lójú rẹ̀, ìgbéraga rẹ̀, ìṣefọ́nńté rẹ̀ àti nípa ọkàn gíga rẹ̀.”+ 
 
-