Àìsáyà 16:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 A ti mú ayọ̀ àti ìdùnnú kúrò nínú ọgbà eléso,Kò sì sí orin ayọ̀ tàbí ariwo nínú àwọn ọgbà àjàrà.+ Ẹni tó ń fẹsẹ̀ tẹ àjàrà kò tẹ̀ ẹ́ mọ́ ní àwọn ibi ìfúntí láti ṣe wáìnì,Torí mo ti mú kí ariwo náà dáwọ́ dúró.+
10 A ti mú ayọ̀ àti ìdùnnú kúrò nínú ọgbà eléso,Kò sì sí orin ayọ̀ tàbí ariwo nínú àwọn ọgbà àjàrà.+ Ẹni tó ń fẹsẹ̀ tẹ àjàrà kò tẹ̀ ẹ́ mọ́ ní àwọn ibi ìfúntí láti ṣe wáìnì,Torí mo ti mú kí ariwo náà dáwọ́ dúró.+