Jeremáyà 48:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ìdùnnú àti ayọ̀ ti kúrò nínú ọgbà elésoÀti ní ilẹ̀ Móábù.+ Mo sì ti mú kí wáìnì dá níbi tí wọ́n ti ń fún wáìnì. Kò sí ẹni tí á máa kígbe ayọ̀ bí wọ́n ṣe ń tẹ̀ ẹ́. Igbe náà máa yàtọ̀ pátápátá.’”+
33 Ìdùnnú àti ayọ̀ ti kúrò nínú ọgbà elésoÀti ní ilẹ̀ Móábù.+ Mo sì ti mú kí wáìnì dá níbi tí wọ́n ti ń fún wáìnì. Kò sí ẹni tí á máa kígbe ayọ̀ bí wọ́n ṣe ń tẹ̀ ẹ́. Igbe náà máa yàtọ̀ pátápátá.’”+