Àìsáyà 16:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé inú mi lọ́hùn-ún ń ru sókè torí Móábù,+Bí ìgbà tí wọ́n ń ta háàpù,Àti inú mi lọ́hùn-ún torí Kiri-hárésétì.+
11 Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé inú mi lọ́hùn-ún ń ru sókè torí Móábù,+Bí ìgbà tí wọ́n ń ta háàpù,Àti inú mi lọ́hùn-ún torí Kiri-hárésétì.+