Àìsáyà 15:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọkàn mi ń ké jáde torí Móábù. Àwọn tó sá níbẹ̀ ti sá lọ sí Sóárì+ àti Ẹgilati-ṣẹ́líṣíyà+ lọ́hùn-ún lọ́hùn-ún. Wọ́n ń sunkún bí wọ́n ṣe ń gòkè lọ sí Lúhítì;Wọ́n ń ké lójú ọ̀nà Hórónáímù torí àjálù náà.+ Jeremáyà 48:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ìdí nìyẹn tí ọkàn mi á fi kédàárò* nítorí Móábù bíi fèrè,*+Ọkàn mi á sì kédàárò* nítorí àwọn ọkùnrin Kiri-hérésì bíi fèrè.* Nítorí ọrọ̀ tí ó kó jọ máa ṣègbé.
5 Ọkàn mi ń ké jáde torí Móábù. Àwọn tó sá níbẹ̀ ti sá lọ sí Sóárì+ àti Ẹgilati-ṣẹ́líṣíyà+ lọ́hùn-ún lọ́hùn-ún. Wọ́n ń sunkún bí wọ́n ṣe ń gòkè lọ sí Lúhítì;Wọ́n ń ké lójú ọ̀nà Hórónáímù torí àjálù náà.+
36 Ìdí nìyẹn tí ọkàn mi á fi kédàárò* nítorí Móábù bíi fèrè,*+Ọkàn mi á sì kédàárò* nítorí àwọn ọkùnrin Kiri-hérésì bíi fèrè.* Nítorí ọrọ̀ tí ó kó jọ máa ṣègbé.