- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 21:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        29 O gbé, ìwọ Móábù! Ẹ máa pa run, ẹ̀yin ará Kémóṣì!+ Ó sọ àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ di ìsáǹsá, ó sì sọ àwọn ọmọbìnrin rẹ̀ di ẹrú Síhónì, ọba àwọn Ámórì. 
 
-