Àìsáyà 21:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú: Inú igbó, nínú aṣálẹ̀ tó tẹ́jú lẹ máa sùn mọ́jú,Ẹ̀yin ará Dédánì+ tó ń rìnrìn àjò. Jeremáyà 25:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí náà, mo gba ife náà lọ́wọ́ Jèhófà, mo sì mú kí gbogbo orílẹ̀-èdè tí Jèhófà rán mi sí mu ún:+ Jeremáyà 25:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Dédánì,+ Témà, Búsì àti gbogbo àwọn tí wọ́n gé irun wọn mọ́lẹ̀ ní ẹ̀bátí,+
13 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú: Inú igbó, nínú aṣálẹ̀ tó tẹ́jú lẹ máa sùn mọ́jú,Ẹ̀yin ará Dédánì+ tó ń rìnrìn àjò.