ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 9:25, 26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Jèhófà sọ pé, “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀ tí màá mú kí gbogbo àwọn tó kọlà* àmọ́ tí wọn ò kọlà* lóòótọ́ jíhìn+ 26 àti Íjíbítì àti + Júdà+ àti Édómù+ àti àwọn ọmọ Ámónì+ àti Móábù+ pẹ̀lú gbogbo àwọn tí wọ́n gé irun wọn mọ́lẹ̀ ní ẹ̀bátí, tí wọ́n ń gbé ní aginjù.+ Nítorí gbogbo orílẹ̀-èdè jẹ́ aláìkọlà,* gbogbo ilé Ísírẹ́lì sì jẹ́ aláìkọlà* ọkàn.”+

  • Jeremáyà 49:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 A ó kó ràkúnmí wọn lọ,

      Ohun ọ̀sìn wọn tó pọ̀ rẹpẹtẹ ni a ó sì kó bí ẹrù ogun.

      Màá tú wọn ká síbi gbogbo,*

      Àwọn tí wọ́n gé irun wọn mọ́lẹ̀ ní ẹ̀bátí,+

      Màá sì mú àjálù wọn wá láti ibi gbogbo,” ni Jèhófà wí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́