1 Àwọn Ọba 9:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ọba Sólómọ́nì tún ṣe ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun ní Esioni-gébérì,+ tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Élótì, ní èbúté Òkun Pupa ní ilẹ̀ Édómù.+
26 Ọba Sólómọ́nì tún ṣe ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun ní Esioni-gébérì,+ tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Élótì, ní èbúté Òkun Pupa ní ilẹ̀ Édómù.+