Jeremáyà 51:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lójijì, Bábílónì ṣubú, ó sì fọ́.+ Ẹ pohùn réré ẹkún fún un! + Ẹ fún un ní básámù nítorí ìrora rẹ̀; bóyá ara rẹ̀ máa yá.” Ìfihàn 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Áńgẹ́lì kejì tẹ̀ lé e, ó ń sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì Ńlá+ ti ṣubú,+ ẹni tó mú kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè mu nínú wáìnì ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́* ti ìṣekúṣe* rẹ̀!”+
8 Lójijì, Bábílónì ṣubú, ó sì fọ́.+ Ẹ pohùn réré ẹkún fún un! + Ẹ fún un ní básámù nítorí ìrora rẹ̀; bóyá ara rẹ̀ máa yá.”
8 Áńgẹ́lì kejì tẹ̀ lé e, ó ń sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì Ńlá+ ti ṣubú,+ ẹni tó mú kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè mu nínú wáìnì ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́* ti ìṣekúṣe* rẹ̀!”+