Jeremáyà 31:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “tí màá bá ilé Ísírẹ́lì àti ilé Júdà dá májẹ̀mú tuntun.+