Sáàmù 137:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́sanLórí ohun tí o ṣe sí wa.+ Ìfihàn 18:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Bó ṣe ṣe sí àwọn míì ni kí ẹ ṣe sí i,+ àní ìlọ́po méjì ohun tó ṣe ni kí ẹ san fún un;+ nínú ife+ tó fi po àdàlù, kí ẹ po ìlọ́po méjì àdàlù náà fún un.+
8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́sanLórí ohun tí o ṣe sí wa.+
6 Bó ṣe ṣe sí àwọn míì ni kí ẹ ṣe sí i,+ àní ìlọ́po méjì ohun tó ṣe ni kí ẹ san fún un;+ nínú ife+ tó fi po àdàlù, kí ẹ po ìlọ́po méjì àdàlù náà fún un.+