- 
	                        
            
            Àìsáyà 47:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Jókòó sílẹ̀ níbi tí kò sí ìtẹ́,+ Ìwọ ọmọbìnrin àwọn ará Kálídíà, Torí àwọn èèyàn ò tún ní pè ọ́ ní ẹlẹgẹ́ àti àkẹ́jù mọ́. 
 
- 
                                        
Jókòó sílẹ̀ níbi tí kò sí ìtẹ́,+
Ìwọ ọmọbìnrin àwọn ará Kálídíà,
Torí àwọn èèyàn ò tún ní pè ọ́ ní ẹlẹgẹ́ àti àkẹ́jù mọ́.