- 
	                        
            
            Jeremáyà 31:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        6 Nítorí ọjọ́ ń bọ̀, nígbà tí àwọn olùṣọ́ tó wà lórí àwọn òkè Éfúrémù máa ké jáde pé: ‘Ẹ dìde, ẹ jẹ́ ká lọ sí Síónì, sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run wa.’”+ 
 
-