ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 2:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ọ̀pọ̀ èèyàn máa lọ, wọ́n á sì sọ pé:

      “Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká lọ sórí òkè Jèhófà,

      Sí ilé Ọlọ́run Jékọ́bù.+

      Ó máa kọ́ wa ní àwọn ọ̀nà rẹ̀,

      A ó sì máa rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀.”+

      Torí òfin* máa jáde láti Síónì,

      Ọ̀rọ̀ Jèhófà sì máa jáde láti Jerúsálẹ́mù.+

  • Jeremáyà 50:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 “Ní àwọn ọjọ́ yẹn àti ní àkókò yẹn,” ni Jèhófà wí, “àwọn èèyàn Ísírẹ́lì àti àwọn èèyàn Júdà máa kóra jọ.+ Wọ́n á máa sunkún bí wọ́n ṣe ń rìn lọ,+ wọ́n á sì jọ máa wá Jèhófà Ọlọ́run wọn.+ 5 Wọ́n á béèrè ọ̀nà tó lọ sí Síónì, wọ́n á yíjú sí apá ibẹ̀,+ wọ́n á ní, ‘Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a bá Jèhófà dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé, tí kò sì ní ṣeé gbàgbé.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́