-
Jeremáyà 51:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ẹ wo bí Bábílónì ṣe di ohun àríbẹ̀rù láàárín àwọn orílẹ̀-èdè!
-
-
Ìfihàn 18:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Àwọn oníṣòwò tó ta àwọn nǹkan yìí, tí wọ́n di ọlọ́rọ̀ láti ara rẹ̀, máa dúró ní òkèèrè torí bó ṣe ń joró bà wọ́n lẹ́rù, wọ́n máa sunkún, wọ́n sì máa ṣọ̀fọ̀, 16 wọ́n á sọ pé, ‘Ó mà ṣe o, ó mà ṣe fún ìlú ńlá náà o, tó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa,* tó ní àwọ̀ pọ́pù àti àwọ̀ pupa, tí wọ́n sì fi àwọn ohun ọ̀ṣọ́ oníwúrà ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ dáadáa, pẹ̀lú àwọn òkúta iyebíye àti péálì,+
-