- 
	                        
            
            Jeremáyà 49:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        25 Báwo ló ṣe jẹ́ pé a kò tíì pa ìlú ìyìn tì, Ìlú ayọ̀? 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Dáníẹ́lì 4:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        30 Ọba ń sọ pé: “Ṣebí Bábílónì Ńlá nìyí, tí mo fi agbára mi àti okun mi kọ́ fún ilé ọba àti fún ògo ọlá ńlá mi?” 
 
-