Àìsáyà 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wọ́n ń bọ̀ láti ilẹ̀ tó jìnnà,+Láti ìkángun ọ̀run,Jèhófà àti àwọn ohun ìjà ìbínú rẹ̀,Láti pa gbogbo ayé run.+ Jeremáyà 51:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Ẹ dán ọfà;+ ẹ gbé àwọn apata ribiti.* Jèhófà ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Mídíà sókè,+Torí ó ní in lọ́kàn láti pa Bábílónì run. Nítorí ẹ̀san Jèhófà nìyí, ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀.
5 Wọ́n ń bọ̀ láti ilẹ̀ tó jìnnà,+Láti ìkángun ọ̀run,Jèhófà àti àwọn ohun ìjà ìbínú rẹ̀,Láti pa gbogbo ayé run.+
11 “Ẹ dán ọfà;+ ẹ gbé àwọn apata ribiti.* Jèhófà ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Mídíà sókè,+Torí ó ní in lọ́kàn láti pa Bábílónì run. Nítorí ẹ̀san Jèhófà nìyí, ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀.