Àìsáyà 13:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá gbé àwọn ará Mídíà dìde sí wọn,+Àwọn tí kò ka fàdákà sí nǹkan kan,Tí wúrà ò sì já mọ́ nǹkan kan lójú wọn. Àìsáyà 45:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba,Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀,Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè:
17 Màá gbé àwọn ará Mídíà dìde sí wọn,+Àwọn tí kò ka fàdákà sí nǹkan kan,Tí wúrà ò sì já mọ́ nǹkan kan lójú wọn.
45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba,Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀,Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè: