Àìsáyà 45:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Màá fún ọ ní àwọn ìṣúra tó wà nínú òkùnkùnÀti àwọn ìṣúra tó pa mọ́ láwọn ibi tí kò hàn síta,+Kí o lè mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tó ń fi orúkọ rẹ pè ọ́.+
3 Màá fún ọ ní àwọn ìṣúra tó wà nínú òkùnkùnÀti àwọn ìṣúra tó pa mọ́ láwọn ibi tí kò hàn síta,+Kí o lè mọ̀ pé èmi ni Jèhófà,Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tó ń fi orúkọ rẹ pè ọ́.+