ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 50:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 “Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ará Kálídíà,” ni Jèhófà wí,

      “Ó dojú kọ àwọn tó ń gbé ní Bábílónì, ó sì dojú kọ àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn ọlọ́gbọ́n rẹ̀.+

  • Jeremáyà 50:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ẹṣin wọn àti àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn,

      Tó sì dojú kọ onírúurú àjèjì tó wà láàárín rẹ̀,

      Wọ́n á dà bí obìnrin.+

      Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ìṣúra rẹ̀, ṣe ni wọ́n á kó wọn lọ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́